Àlàyé nípa Ètò Bíbélì

Àwon Òtá OkànÀpẹrẹ

Enemies Of The Heart

Ọjọ́ 1 nínú 5

Andy Staney: Àwọn ọ̀tá ọkàn náà<


Ètò ti Ọjọ́ kínní


"Onina tí ó ngbáradì àti bú jáde


Ibi kíkà: Mátíù 15:1-20


Ó ṣeé ṣe fún wa pé kí á máa ṣọ́ ìhùwà sí wa ní gbà tí a kò kọbiara sí ọ kàn wa. Lóòtọ́, bá wo ni o ṣe lè ṣọ́ ọkàn rẹ? N o mò leè hùwà ré kọjá tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ tí ẹnìkan kò ní. pe àkíyèsí mi síi.Ṣùgbọ́n ọkàn mi? Eléyìí nira díẹ̀


Jésù sọ ohun kan tí o ní ipa tó gbògì títí dòní. "Ohun ti o jáde láti enu Ènìyàn wá láti inú ọkàn", àti pé, láti inú ọkàn ni èrò búburú ti ń jáde wá".


Ọkàn jẹ́ àdìtú tó bẹ́ẹ̀. Lòòtọ́ Wòólì bèrè nípa O̩kàn, ó ní, "Ta ló leè nÍ òye rẹ̀?" (Jeremaya 17:9). Ìbéèrè tí o dár jù lọ. Èyí jámọ́ sípé kòsí. Èyí tí mo fara mọ́. Tí a bánía ti bè̩rẹ̀ sí ní òye rẹ̀, ó dájú a kò leè ṣàkóso. rẹ̀-ìdí nìyí tí agbọ́dọ̀ kọ́ láti máa ṣọ́ọ. Gẹ́gẹ́bí ilẹ̀ gbígbóná ríru ti onina tí gbaradì ríru. ohun tí o kò mọ̀.
leèfa ọgbẹ́ fún ọ


Láìròtẹ́lẹ̀ ẹnìkan leè pinnu ìtúká nínú ìgbeyàwó.


Láìròtẹ́lẹ̀ìlọsíwájú nínú ẹ̀kó̩ lè mẹ́hẹ kí ìhùwàsí yí padà.


Láìròtẹ́lẹ̀ìwà tútù ìgbà kan di aṣekúpani


Lójúẹsẹ̀ọ̀rọ kòbákùngbé a ya ọkàn olùfẹ́ tí kò fura.


A ti ríi rí, ó ti ṣẹlẹ̀ sí wa rí, a sì ti jẹ̀bi rẹ̀ rí. Gẹ́gẹ́bí Jésù ti sọ àsọtẹ́tẹ̀ rẹ̀, hun tí o bẹ̀rẹ̀ ní kọ́lọ́én ọkàn wa kì yóò a mọ́ títí. Àsẹ̀yìn wá àsẹ̀yìn bọ̀ yóò rúlẹ̀ wọlé, ibi iṣẹ́ àti àwọn agbègbè wa


Ọkàn a máa to jú bọ gbogbo ìtàkùrọ̀ sọ. A máa ṣatọ́nà gbogbo ìbádọ́rẹ̀ẹ́. Ìgbésí ayé wa ń tọkàn wá. A sì ńlo igbésé ayé wa, ìtọ́ni, ìdarí, ìbádọ́rẹ́, ìbáṣepọ̀, ojúkọ, takìjí, fèsì, pàṣẹ, ṣàkóso, ṣe ìyajú, àti fẹ́ràn láti inú ọkàn. Ọkàn wa ni ipa órí ìgbóná ìsọ̀rọ̀ sí wa, ọkàn wa ni agbára láti ṣàserékọjá hun tía kún dùn tàbí èyí tí a ò kún dùn. Gbogbo ibi ìloayé máa ṣe pàdé mpàdé pẹ̀lú ohun tí ó nlọ nínú o̩kàn wa. Ohun gbogbo a máa gbabẹ̀. kọjà lọ si bi tí wọ́n ńlọ. Ohun gbogbo.


A ní lò ìgboyà láti bèèrè ìrànlọ́wọ́ Baba waọ̀run láti ṣọ́, ní òye, àti wẹ ọkàn wa. Oun ṣe tàn láti áhùn kí o sì fi hàn wa bi a óò ti pààrọ̀ ìwà úburú átijọ́ ti ọkàn pẹ̀lú tuntun àti èyí tí ó dára tí yóò mú wa dà bí ọmọ rẹ̀.


Nínú ọjọ́ mẹ́rin síi ti ètò yí, a yóò máa ṣàyẹ̀wò àwọn ọ̀tá ọkàn mẹ́rin tí gbogbo ènìyàn ń dojù kọ.


Kíni àwọn èrò ọkàn rẹ lọ́wọ́lọ́wọ́, ọ̀rọ̀, àti àwọn ìṣe n fhàn nípa ohun tí o ń lọ ní ọkàn rẹ? Bèrè lọ́wọ́ ẹnìkan tí o sún mọ́ọ ohun ti wọ́n lè rí sí èyí pẹ̀lú.


Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2

Nípa Ìpèsè yìí

Enemies Of The Heart

Gẹ́gẹ́ bíi ọkàn tí ara to méwulọ́wọ́ lè pa ara wa run, ọkàn tọ́ méwulọ́wọ́ nípa tí èrò - ìmọ̀lára àti nípa tẹ́mí lè pá ìwọ àti àwọn àjọṣe rè run. Fún ọjọ́ márùn-ún tó ń mbò, jẹ́ kí Andy Stanley rán ẹ lọ́wọ́ láti wò inú a...

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Andy Stanley àti Multnomah fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ lọ sí: bit.ly/2gNB92i

YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa