Ka Ọ̀rọ̀ Ọlọrun pẹ̀lú Ètò-ìṣiṣẹ́ Bíbélì

Máa mú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run dání níbikíbi tó o bá lọ nípa ṣíṣàtìlẹyìn Bíbélì App lọ́fẹ̀ẹ́. Tẹ́tí sí ohùn Bíbélì, ṣe Àdúrà, kẹ́kọ̀ọ́ pẹ̀lú Àwọn Ọ̀rẹ́, àti púpọ̀ sí i fún ọ̀fẹ́. O lè yan èyí tó o fẹ́ nínú àwọn ìtumọ̀ Bíbélì tó lé ní ẹgbẹ̀rún méjì àti irínwó [2,400]. O lè ka Bíbélì ní èdè tó ju ẹgbẹ̀jọ [1,600] lọ lórí kọ̀ǹpútà rẹ, fóònù tàbí tabulẹti.

Ṣe ìtìlẹyìn Bible App Báyìí

100% LỌ́FẸ̀Ẹ́. KÒ SÍ ÌPOLÓWÓ TÀBÍ ÌRAJÀ KANKAN.

googleiosamazon
Ṣe Ìgbàsílẹ̀ Ohun Èlò náàṢe Ìgbàsílẹ̀ Ohun Èlò náà

Fi fóònù tàbí tabulẹti rẹ ṣe àtẹ̀jíṣẹ́ àmì QR yìí kó o lè gba Bible App.

Apá Ìsọfúnni
googleappamazon

Máa ka Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Ẹ darapọ̀ mọ́ àwùjọ àgbáyé kan tó ní àwọn èèyàn tó lé ní àádọ́ta mílíọ̀nù:

Mo ní Ọ̀rọ̀ náà nígbà gbogbo.

Mo ti pààlà sí àwọn àyọkà tó ṣe pàtàkì sí mi. Kódà, mo ti ka gbogbo rẹ̀ tán láàrin ọdún kan, ọpẹ́ lọ́wọ́ ètò ẹ̀kọ́ kíkà.

Mo f'ọwọ́ rẹ̀ s'ọ̀yà

Mo fẹ́ràn ààfàní láti kàn sí àwọn ọ̀rẹ́ àti pé àwọn ètò ẹ̀kọ́ kíkà Bibeli yìí l'ákáakì. Ohun èlò yìí tún ràn mí lọ́wọ́ láti dúró déédé ní kíka wọ́n nítorí ó ní àwọn aránnilétí fún àwọn ètò náa. Ó tún fún mi ní ọ̀nà mìíràn láti súnmọ́ Ọlọ́run. Ṣe àgbàsílẹ̀ èyí kí o sì kàá lójoojúmọ́!

Ohun èlò àgbàyanu.

Ohun èlò ńlá pẹ̀lú oríṣiríṣi ẹ̀dà Bíbélì láti yàn nínú wọn. ... Àwọn Àkáálẹ̀ ohùn Bíbélì náà yááyì, ó sì rọrùn láti gbọ́ l'ágbọ̀yé.

Ó dáa báun. Ìlọsíwájú gbogbo ìgbà!

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìtumọ̀ àti èdè ló wà, àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ èyí tí a lè ṣe àtúnyẹ̀wò láti kà láìlo ìkànnì. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ohun èlò tó wúlò, bíi agbára láti ṣe àkọsílẹ̀ àti àwọn àmì ojú ìwé.

Ohun Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tó dára jù lọ!

Mo nifẹ bi o ṣe ni ọpọlọpọ awọn ẹya ati pe awọn ẹsẹ ti ọjọ wa, awọn igbẹkẹle, awọn ero ati agbegbe. O ṣeun fún ohun èlò yìí. :)

Àwọn ìtumọ̀ bíi mélòó kan àti kíkà tí kò sí ní ìkànnì!

Ó dára gan-an nítorí pé oríṣiríṣi àdàkọ ni ó wà, mo sì lè gba oríṣiríṣi àdàkọ láti kà á láìní ìkànnì. Mo lè máa fetí sí ohun èlò yìí.

Ohun elo tó dáa!

Ó jẹ́ kí n túbọ̀ máa ka Bíbélì. Mo fẹ́ràn wíwá àti pínpín àwọn àkànṣe àti oríṣiríṣi ọ̀nà láti pínpín. Bákan náà ni wọ́n ṣe ń ṣe àwo orin náà.

Ohun elo tó dáa

Èyí jẹ́ ohun èlò tó dára gan-an fún kíkẹ́kọ̀ọ́ látinú onírúurú ìtumọ̀ Bíbélì. Ó tún wúlò fún gbígbọ́ Bíbélì nígbà tó o bá ń wakọ̀.

Ohun èlò Bíbélì tó dára jù lọ!

Èyí ni ohun èlò Bíbélì tó dára jù lọ. Ó ní ọ̀rọ̀ náà ní onírúurú èdè àti ìtumọ̀ fún lílò lórí-ìkànnì àti láìsí ìkànnì. Ó ní àwọn ọ̀rọ̀ ìfọkànsìn fún gbogbo nǹkan tó o lè ronú kàn. Wàá lè bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀, wàá sì lè kẹ́kọ̀ọ́ nípa Ọlọ́run àti Ọ̀rọ̀ rẹ̀.

YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa