Àlàyé nípa Ètò Bíbélì

Ìmọ̀lára Mímọ́ - Èsì Látinú Bíbélì sí Ìpèníjà GbogboÀpẹrẹ

Holy Emotions - Biblical Responses to Every Challenge

Ọjọ́ 1 nínú 30

Òtítọ́ tó yanilẹ́nu ni: A bí ọ ṣ'áyé, ní àkókò yìí nínú ìtàn-àkọọ́lẹ̀, láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run fún àwọn èrò àti àwọn ìpinnu Rẹ. Ó nílò ẹnìkan bíi tìrẹ láti nífẹ̀ẹ́ ẹni tí a kò nífẹ̀ẹ́ sí—láti mú ayọ̀ wá sínú ayé òkùnkùn, òtútù – láti fi àlááfíà hàn nínú àwọn ìfọ̀rọ̀wérọ̀ tí ń dani láàmú àti àwọn ipò – àti láti jẹ́ onínúure nígbà tí àṣà ìbílẹ̀ wa bá di ohun mí a kò rò. Ọlọ́run, Ẹlẹ́dàá àgbáyé, nílò ẹnì kan gẹ́gẹ́ bí ìwọ láti máa ní ìrètí nígbà gbogbo ní ojú àwọn ipò ìjákulẹ̀ –láti nírètí nígbà tí kò sí ìdí fún ìrètí – àti láti fi sùúrù hàn sí àwọn agídí àti àwọn ènìyàn ọ̀ṣọ́. Nítorípé Ọlọ́run nílò rẹ, Ó dá ọ láti fi ọkàn Rẹ hàn. Ìṣòro náà ni pé, gẹ́gẹ́ bí àwọn ọmọ tirẹ̀ gan-an, a ti ní ọ̀pọ̀ àbùdá apilẹ̀ àbùdá ti ayé a sì ti kọ àwọn ànímọ́ tí Ọlọ́run, Bàbá onífẹ̀ẹ́, tí a bù lé lọ́lá tì. Ìṣòro náà ni pé, a yóò kúkú ní ní ọnà wa ju ọnà Rẹ lọ. Ìṣòro náà ni pé, a yóò kúkú fọwọkan ìrisi ìmọtara-ẹni lórí ipò kan ju láti ṣàfihàn èsò aládùn àti àdídùn. Ọlọ́run ló dá wa láti fi ọkàn rẹ̀ hàn ní àkókò kan ṣoṣo yìí ní gbogbo àkókò tí a kọ sílẹ̀.



A ṣẹ̀dá wa láti ṣe àwọn iṣẹ rẹ́re Rẹ ṣùgbọn dípò, a ti pinnu láti yípadà sínú irọ́ ti ẹni tí Ó pinnu fún wa láti jẹ. Ọlọ́run dá wa nítorí àìsí “Iwa bii Ọlọ́run” wà lórí ilẹ̀ ayé, nítorí náà ó rán ọ, Ó sì rán mi. Ọlọ́run yóò fi ara Rẹ̀ hàn nípasẹ wa ní ìwọ̀nba tí a bá gbà láàyè láti kún gbogbo igun ọkàn àti ìgbésí ayé wa. Òtítọ́ ńlá ni pé o le ní púpọ̀ ti Ọlọrun bí o ṣe le fẹ! Ìbéèrè náà kò yípadà rárá láti Ọgbà Édẹ́nì títí di òní, Báwo ni o ṣe Fẹ́ Olọ́run si?

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2

Nípa Ìpèsè yìí

Holy Emotions - Biblical Responses to Every Challenge

Ọlọ́run dá ọ Ó sì fi ọ sí àyè tí o wà ní irú àkókò yìí, to love the unlovable, bii àlàáfíà nínú rúkè rúdò, kí o sì fi ayọ̀ tí kò ṣeé dẹ́kun nínú ìṣẹ̀lẹ̀ gbogbo. À ti ṣe bẹ́ẹ̀ lè jọ pé kò ṣeéṣẹ, ṣùgbọ́n o le è ṣeé tí o bá...

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Carol McLeod and Just Joy Ministries fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọwọ lọsí: www.justjoyministries.com

YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa