Fún Iṣẹ́ Rẹ̀ ní Ìtunmọ̀

Fún Iṣẹ́ Rẹ̀ ní Ìtunmọ̀

Ọjọ́ 4

Púpọ̀ nínú wa ni yíò lo bi ìdajì aiyé wa lágbà lẹ́nu iṣẹ́. Afẹ́ mọ̀ wípé iṣẹ́ wa ní ìtunmọ́ pé iṣẹ́ wa ṣẹ kókó. Ṣùgbọ́n áapon, ìpèníjà àti ìpọ́njú le mú kí a rí isẹ́ bi ohun líle tí aní láti là kọjá. Ètò yí yíò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti mọ agbára tí o ní láti yan ìtunmọ̀ rere tí ó gbilẹ̀ nínú ìgbàgbọ́ fún iṣẹ́ re

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Workmatters fún ètò yíi. Fún àlàyé síi, jọ̀wọ́ lọsí: http://www.workmatters.org/workplace-devotions/
Nípa Akéde

YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa