Wíwá Ọkàn Ọlọ́run Lójoojúmọ́ - Ọgbọ́n

Wíwá Ọkàn Ọlọ́run Lójoojúmọ́ - Ọgbọ́n

Ọjọ́ 5

Wíwá Ọkàn Ọlọ́run Lójoojúmọ́ jẹ́ ètò ẹ̀kọ́ kíkà ọlọ́jọ́ 5 tí a ṣètò rẹ̀ láti ru 'ni sóké, pe'ni níjà àti láti ràn wá lọ́wọ́ lójú ọ̀nà ìgbé-ayé ojoojúmọ́. Gẹ́gẹ́ bí Boyd Bailey ṣe sọ, " Wá A kódà nígbàtí kò wù ọ́ ṣe, tàbí nígbàtí ọwọ́ rẹ kún fún iṣẹ́, Òun yíó sí san ọ l'ẹ́san ìjẹ́ olódodo rẹ." Bíbélì sọ pé, "Ìbùkún ni fún àwọn tí ńpa ẹ̀rí Rẹ̀ mọ́, tí sì ńwá A kiri tinú-tinú gbogbo." Sáàmù 119:2

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Boyd Bailey pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Wisdom Hunters fún ìpèsè ètò yí. Fún àlàyé síwájú síi jọ̀wọ́ kàn sí: https://www.wisdomhunters.com/
Nípa Akéde

YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa