Joh 1:12
Joh 1:12 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn iye awọn ti o gbà a, awọn li o fi agbara fun lati di ọmọ Ọlọrun, ani awọn na ti o gbà orukọ rẹ̀ gbọ́
Pín
Kà Joh 1Joh 1:12 Yoruba Bible (YCE)
Ṣugbọn iye àwọn tí ó gbà á, ni ó fi àṣẹ fún láti di ọmọ Ọlọrun, àní àwọn tí ó gba orúkọ rẹ̀ gbọ́.
Pín
Kà Joh 1